DAISY STORIES YORUBA

DAISY, OPAL
AND ARRANGER STORIES
  
Short stories in English translated into many languages in a convenient parallel text format to help you learn them more quickly and easily.

TRANSLATED INTO:
 
AFRIKAANS
The Search for Lorna 
Daisy Macbeth
The Surprise
The Nightwatch
A Nice Little Trip

The Bookworm

A Matter of Justice

ALBANIAN
The Search for Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth
A Nice Little Trip
The Nightwatch
The Oak
The Bookworm
Imogen
The Mumbling Man

ARABIC
The Search for Lorna 
The Surprise
1
The Surprise 2
Daisy Macbeth

The Nightwatch
A Nice Little Trip

BENGALI
The Surprise

BOSNIAN
The Search for Lorna
The Surprise

BRASILIAN
The Search for Lorna
The Surprise
The Bookworm
The Wedding
Daisy Macbeth

BULGARIAN
The Search for Lorna

The Surprise
Daisy Macbeth
A Nice Little Trip
The Nightwatch

CHINESE
The Search for Lorna
The Surprise
The Bookworm
ARRANGER STORIES
The Auction

CREOLE
The Search for Lorna 
The Surprise

Daisy Macbeth

CROATIAN
The Search for Lorna
The Surprise

CZECH
The Search for Lorna 
The Surprise

Daisy Macbeth
The Nightwatch
A Nice Little Trip
The Bookworm
The Oak
Imogen
The Green Lodge
A Matter of Justice

DANISH
The Search for Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth
The Nightwatch
A Nice Little Trip
The Bookworm

The Oak

DUTCH
The Search for Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth
The Nightwatch

The Bookworm

ESPERANTO
The Search for Lorna
Daisy Macbeth
The Surprise
The Nightwatch

FINNISH
The Search for Lorna 
The Surprise

The Nightwatch

FRENCH
The Search for Lorna
The Surprise
The Nightwatch
A Nice Little Trip
The Bookworm
The Oak
Imogen

GERMAN
The Search for Lorna
Daisy Macbeth
The Surprise
The Nightwatch
A Nice Little Trip
The Bookworm

ARRANGER STORIES
The Auction

GREEK
The Search for Lorna
Daisy Macbeth
The Surprise
The Nightwatch mp3
A Nice Little Trip mp3
The Bookworm mp3
ARRANGER STORIES
The Auction

HEBREW
The Search for Lorna 1
The Search for Lorna 2
The Surprise

Daisy Macbeth

The Nightwatch

A Nice Little Trip

HINDI
The Search For Lorna
The Surprise

HUNGARIAN
The Search for Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth

The Nightwatch
A Nice Little Trip
The Bookworm

INDONESIAN
The Search for Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth
A Nice Little Trip

ITALIAN
The Search For Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth
The Nightwatch
A Nice Little Trip
The Bookworm
The Oak
Imogen
The Mystery of
Green Lodge

A Matter of Justice

JAPANESE
The Search For Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth

KOREAN
The Search for Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth
The Nightwatch
A Nice Little Trip
The Bookworm

The Oak
Imogen

LUGANDA
The language spoken
in Uganda
The Search for Lorna
The Surprise

MONGOLIAN
The Search for Lorna
 
The Oak  

NORWEGIAN
The Search for Lorna

POLISH
The search for Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth
The Nightwatch

The Oak 1
The Oak 2
The Bookworm
A Nice Little Trip
The Mystery of
Green Lodge

The Wedding
A Matter of Justice
ARRANGER STORIES
The River Mist
The Auction

PORTUGUESE
The Search for Lorna
The Surprise

ROMANIAN
The Search for Lorna
The Surprise

RUSSIAN
The Search for Lorna 1

The Search for Lorna 2
The Surprise
The Nightwatch 1

The Nightwatch 2
Daisy Macbeth
The Oak

SERBIAN
The Nightwatch
The Oak

SPANISH
The Search for Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth

The Nightwatch
A Nice Little Trip
The Bookworm

The Oak
Imogen
The Mystery of
Green Lodge

The Wedding 1
The Wedding 2
A Matter of Justice 1
A Matter of Justice 2
The Serial Killer
ARRANGER STORIES
The Auction
The River Mist
OPAL STORIES
Upside Down

SWEDISH
The Search for Lorna 1

The Search for Lorna 2
The Surprise
Daisy Macbeth
The Nightwatch

The Bookworm

THAI
The Nightwatch
A Nice Little Trip
The Bookworm

Daisy Macbeth

TURKISH
The Search for Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth
The Nightwatch
A Nice Little Trip
The Bookworm
The Mumbling Man
The Oak
A Matter of Justice

UKRAINIAN
The Search for Lorna
Daisy Macbeth

URDU
The Search for Lorna

VENETO 

The Search for Lorna

YORUBA
The Search for Lorna
The Surprise
The Nightwatch

ZULU
The Search for Lorna

CLICK OR TOUCH FOR THE  
THE SURPRISE
Iyalnu Naa
THE DAISY STORIES by Crystal Jones © 1995-2018

.Translation volunteered by: Olofa Adedamola
Emails:
 olofaisrael@yahoo.com  olofaisrael@gmail.com

WITH A VERY BIG THANK YOU FROM THE LONWEB TEAM!
Iyalnu Naa The surprise

 Deesi gbé foonu ó si gbiyanju lati tun pè oníbàárà rẹ leekan si.

Daisy picked up the telephone and tried to get through to her client again.

 Oníbàárà rẹ, ni Franki Baksini kan bayii, ti o ní ilé-ẹru nla kan fun awọn ohun èlò-ina, kò tii sanwó fun ise ọjọ méjì ti oun se fun un. 

Her client, a certain Frank Baccini, who had a warehouse of electrical goods, had not paid for her two days' work.

 Deesi ti  tiraka lati se awari ibi ti alailootọ ẹnikeji Ọgbẹni Baksini n gbé bayii o sì n fi taratara reti sọwedowo rẹ.

Daisy had managed to discover where Mr. Baccini's dishonest partner was now living and was anxiously expecting her cheque.

 Deesi ti bẹrẹ si ni rò o pé àfàìmọ ki       Oníbàárà oun pẹlu naa má jẹ alaisootọ.

Daisy was beginning to think that her client was dishonest too.

 Ohun kan bi ẹni ti nnkan sú, dáhùn ni odikeji foonu, “Hẹlo, ki ni ẹ fẹ?”

A very bored "Hello, can I help you?" was the reply at the other end.

 Ohùn ọdọbínrin kan tii se akọwe Franki Baksini ni.

It was a young woman's voice, Frank Baccini's secretary.

 “Jọwọ, mo fẹ ba Ọgbẹni Baksini sọrọ,”  

"I'd like to speak to Mr. Baccini, please."

 “E má bínú o, Ọgbẹni Baksini kò si ni ilé.”

"Sorry, Mr. Baccini is out of town."

Deesi takú, o ni “amọ, igba wo ni yoo padà dé?

"But when is he coming back?" insisted Daisy.

 “Emi kò mọ o”        

"I'm afraid I don't know."

 “N jẹ o le sọ fun un pé Deesi Hamitin pè e sori aago maa sì fẹ lati ba a sọrọ ni kánkán.” 

"Will you tell him Daisy Hamilton telephoned and would like to talk to him urgently."

 “Kò burú, ó dara mo rò bẹẹ” ni gbogbo èsì kò-kàn-mi ti ó fun un.

"Well - yes, I suppose so," was the completely unconcerned reply.

  Eyi ni ìpè sorí foonu ẹlẹkẹwaa ti Deesi maa ni laarin ọsẹ meji pelu ọdọbínrin yii, sugbon Franki Baksini kò tii kàn si i paapaa.

This was the tenth telephone conversation Daisy had had in two weeks with this young woman, but Frank Baccini hadn't got in touch with her yet.

 Inu bi Deesi, o si pinnu lati lọ si ile-ẹru Ọgbẹni Baksini ki oun lè mọ ti ó bá  wà nibẹ.

Daisy was furious and decided to go to Mr. Baccini's warehouse to see if he was there.

 Nigbati ó dé ibẹ, o kàn ilẹkun ọọfisi naa.

When she arrived, she knocked on the office door.

 Pelu ohun ma-yọ-mi-lẹnu rẹ, Akọwe Baksini wi pe, “Wọle wá.”

Mr. Baccini's secretary said in her monotonous voice: "Come in."

 “Mo ti pè sori aago ni aimoye igba – emi ni Deesi Hamitin.”

"I've telephoned many times - my name is Daisy Hamilton."

 “Lootọ? Tani o fẹ ba ni gbolohun?” ọdọbinrin naa beere lai tilẹ bojuwo Deesi.

"Really? Who did you want to speak to?" asked the young woman without even glancing at Daisy.

 Deesi fèsì pé, Ọgbẹni Baksini ni mo fẹ ba ni gbolohun.

"I want to speak to Mr. Baccini," replied Daisy.

 Kódà ó tilẹ ti mura ìjà sí i.

She was becoming even more aggressive.

 Pelu ohun ma-yọ-mi-lẹnu rẹ naa, o wi pe, “Ko si ni ibi o.” Ó sì tun n kà iwe-irohin rẹ lọ. 

"I'm afraid he's not here," said the secretary in her usual monotonous way and went on reading her magazine.

 Deesi wi pelu ariwo pe, “Ó tó gẹẹ bayii”, ó sọ ilẹkun gbà-à. 

Daisy shouted "Enough is enough!" and banged the door closed.

 Ọkàn Deesi kaarẹ lọpọlọpọ.

Daisy felt rather depressed.

 “Mo mọ ohun ti maa se,” Maa fẹsẹ kan duro ni isọ Luigi fun kétíya ọlọgẹdẹ kan ti o dọsọ.

"I know what I'll do," she thought, "I'll stop off at Luigi's for a nice banana split."

 Deesi fẹran lati maa jokoo si isọ kétíya Luigi, ki ó sì takurọsọ diẹ pẹlu onisọ yii, ti ó jẹ ara Itali kan ti ki i se elérò buburu

Daisy liked sitting in Luigi's ice-cream parlour and having a little chat with the owner, a positive-thinking Italian.

 Bi Deesi se mú òkè gùn lọ si ọọfisi rẹ, ọrọ ti o jẹ mọ awon ọmọ eniyan kò dùn un mọ.

As Daisy walked up the stairs to her office she felt a little less sore about human beings.

 Bi Deesi se n paarọ bàtà rẹ lọwọ sí sálúbàtà, bẹẹ ni ẹnikan kàn ilẹkun ti ó si wọle wá.

Just as Daisy was changing her shoes to a more comfortable pair, someone knocked on the door and walked in.

 Onisẹ kan ti ó wọ asọ isẹ toketilẹ ni

It was a workman in overalls.

 “Omidan, ẹ jọwọ se ẹyin ni Omidan Deesi Hamitin? Nibo ni ki a gbé awọn eleyii kalẹ sí?” ó n na ọwọ sí àpótí nla meji ti n bẹ ni idasẹle àbágòkè.

"Excuse me miss - are you Miss Daisy Hamilton? Where shall we put these?" pointing to two large boxes on the landing.

 Bẹẹ ni, emi ni Omidan Deesi Hamitin sugbọn ki ni awọn ohun ti ó wà ninu awọn àpótí nibẹ yẹn?”

"Yes, I am Daisy Hamilton but what have you got there - what's in those boxes?"

 “Ẹrọ amu-nnkan-tutú ni eyi ti o tobi yii, kekere sì jẹ ẹrọ ti n pò ẹlẹrindodo. Awọn ti o yàn yii dara o, se o mọ, iru awọn ti ó dara jù ni arọwọto ni yii.”  

"The big one is a fridge and the smaller one is a cappuccino-making machine. You've chosen well, you know, these are the best makes around."

Deesi lọgun pe “Emi ò sọ pe mo fẹ rà awọn yii o,”

"I haven't ordered either of these," exclaimed Daisy.

 “Onisẹ fi dandan mu u pe “Sugbọn orukọ rẹ ni n bẹ lori iwe ẹrù!”

"But it's your name on the delivery note!" insisted the workman.

 “Gbogbo owó ni ó ti wà ni àsanpé. Sá sọ ibi ti maa gbe wọn kalẹ si.”

"It's all paid for - just tell me where to put them."

 Ó kù diẹ ki Deesi kọ awọn ẹrù yii nigbati ó ri ti Franki Baksini pẹlu n wọle bọ wá.

Daisy was just about to refuse the goods when she saw Frank Baccini coming in the door, too.

 “Omidan Hamitin. Mo tọrọ aforijin pe mi ò kàn si ọ lati igba yii wá.

"Miss Hamilton. I'm very sorry I haven't been in touch.

 “Mo rò pe kò bi ọ ninu, mo ti sakiyesi pe o ò ni ẹrọ amu-nnkan-tutú ninu ọọfisi rẹ ati…… ẹrọ ti n pò ẹlẹrindodo yii jẹ iru eyi ti kò wọpọ.

"I do hope you don't mind but I had noticed you didn't have a fridge in your office and... this cappuccino-making machine is a little specialty.

 “O, tilẹ wò naa, sọwedowo rẹ ni yii fun isẹ ribiribi ti o se, pẹlu èènì owó diẹ fun awọn ìnáwó pẹpẹpẹ rẹ”

"Oh, by the way here is your cheque for the excellent work you did, with a little extra for your expenses."

 Franki Baksini ri pe ẹnu ya Deesi, ó fi kun ọrọ pe:

Frank Baccini saw Daisy was astonished and added:

 “Mo lero pe akọwe mi ti maa pe ọ? “Mo lọ irin ajo lati bi ọsẹ meloo diẹ lati lọ gbadun pẹlu iyawo mi tuntun.”

"My secretary did phone you, I hope? I've been away for a couple of weeks on honeymoon."

 Deesi yara sara rẹ giri, Rara, ko buru, kò pè mi –  amọ ko si iyọnu, Ọgbẹni Baksini.

Daisy recovered herself, "Well, no, she didn't - but that's quite all right Mr. Baccini!"

VOLUNTEER A TRANSLATION USING THE TEMPLATES PROVIDED HERE!

Lonweb.org has been online since 1997 and has always managed to remain a not-for-profit website offering all its resources for free. Most Daisy Stories, Arranger Stories and Opal Stories have been translated by volunteers. Would you like to become one of them? You can start right away following a couple of very simple instructions: when translating the Daisy, Arranger or Opal Stories please use the templates provided below and fit your translation into the parallel text slots provided. After completion, please send your translation to robertocasiraghi AT elingue DOT net, it will be published in a matter of days.

DAISY STORIES TEMPLATES
The Search for Lorna
The Surprise
Daisy Macbeth
Night Watch
A Nice Little Trip
The Bookworm
The Oak
Imogen
The Mystery of
    Green Lodge

A Matter of Justice
The Wedding
Craig
The Mumbling Man
The Old Manor House
    Ghost

Amy
The Serial Killer
The Mysterious Hand
The Lost Cat
Too Many Cakes Spoil
    the Dough

The Lost Collection Box
Heatwave
The Spin Doctor
Glynn

ARRANGER STORIES TEMPLATES
The Auction
The River Mist
Halloween

OPAL STORIES TEMPLATES
Upside Down
Parallel Homes
Different Existences
East is West and West
    is East

VERSION OPTIMISED FOR MOBILE PHONES

Iyalẹnu Naa The surprise

 Deesi gbé foonu ó si gbiyanju lati tun pè oníbàárà rẹ leekan si.

Daisy picked up the telephone and tried to get through to her client again.

 Oníbàárà rẹ, ni Franki Baksini kan bayii, ti o ní ilé-ẹru nla kan fun awọn ohun èlò-ina, kò tii sanwó fun ise ọjọ méjì ti oun se fun un. 

Her client, a certain Frank Baccini, who had a warehouse of electrical goods, had not paid for her two days' work.

 Deesi ti  tiraka lati se awari ibi ti alailootọ ẹnikeji Ọgbẹni Baksini n gbé bayii o sì n fi taratara reti sọwedowo rẹ.

Daisy had managed to discover where Mr. Baccini's dishonest partner was now living and was anxiously expecting her cheque.

 Deesi ti bẹrẹ si ni rò o pé àfàìmọ ki       Oníbàárà oun pẹlu naa má jẹ alaisootọ.

Daisy was beginning to think that her client was dishonest too.

 Ohun kan bi ẹni ti nnkan sú, dáhùn ni odikeji foonu, “Hẹlo, ki ni ẹ fẹ?”

A very bored "Hello, can I help you?" was the reply at the other end.

 Ohùn ọdọbínrin kan tii se akọwe Franki Baksini ni.

It was a young woman's voice, Frank Baccini's secretary.

 “Jọwọ, mo fẹ ba Ọgbẹni Baksini sọrọ,”  

"I'd like to speak to Mr. Baccini, please."

 “E má bínú o, Ọgbẹni Baksini kò si ni ilé.”

"Sorry, Mr. Baccini is out of town."

Deesi takú, o ni “amọ, igba wo ni yoo padà dé?  

"But when is he coming back?" insisted Daisy.

 “Emi kò mọ o”        

"I'm afraid I don't know."

 “N jẹ o le sọ fun un pé Deesi Hamitin pè e sori aago maa sì fẹ lati ba a sọrọ ni kánkán.” 

"Will you tell him Daisy Hamilton telephoned and would like to talk to him urgently."

 “Kò burú, ó dara mo rò bẹẹ” ni gbogbo èsì kò-kàn-mi ti ó fun un.

"Well - yes, I suppose so," was the completely unconcerned reply.

  Eyi ni ìpè sorí foonu ẹlẹkẹwaa ti Deesi maa ni laarin ọsẹ meji pelu ọdọbínrin yii, sugbon Franki Baksini kò tii kàn si i paapaa.

This was the tenth telephone conversation Daisy had had in two weeks with this young woman, but Frank Baccini hadn't got in touch with her yet.

 Inu bi Deesi, o si pinnu lati lọ si ile-ẹru Ọgbẹni Baksini ki oun lè mọ ti ó bá  wà nibẹ.

Daisy was furious and decided to go to Mr. Baccini's warehouse to see if he was there.

 Nigbati ó dé ibẹ, o kàn ilẹkun ọọfisi naa.

When she arrived, she knocked on the office door.

 Pelu ohun ma-yọ-mi-lẹnu rẹ, Akọwe Baksini wi pe, “Wọle wá.”

Mr. Baccini's secretary said in her monotonous voice: "Come in."

 “Mo ti pè sori aago ni aimoye igba – emi ni Deesi Hamitin.”

"I've telephoned many times - my name is Daisy Hamilton."

 “Lootọ? Tani o fẹ ba ni gbolohun?” ọdọbinrin naa beere lai tilẹ bojuwo Deesi.

"Really? Who did you want to speak to?" asked the young woman without even glancing at Daisy.

 Deesi fèsì pé, Ọgbẹni Baksini ni mo fẹ ba ni gbolohun.

"I want to speak to Mr. Baccini," replied Daisy.

 Kódà ó tilẹ ti mura ìjà sí i.

She was becoming even more aggressive.

 Pelu ohun ma-yọ-mi-lẹnu rẹ naa, o wi pe, “Ko si ni ibi o.” Ó sì tun n kà iwe-irohin rẹ lọ. 

"I'm afraid he's not here," said the secretary in her usual monotonous way and went on reading her magazine.

 Deesi wi pelu ariwo pe, “Ó tó gẹẹ bayii”, ó sọ ilẹkun gbà-à. 

Daisy shouted "Enough is enough!" and banged the door closed.

 Ọkàn Deesi kaarẹ lọpọlọpọ.

Daisy felt rather depressed.

 “Mo mọ ohun ti maa se,” Maa fẹsẹ kan duro ni isọ Luigi fun kétíya ọlọgẹdẹ kan ti o dọsọ.

"I know what I'll do," she thought, "I'll stop off at Luigi's for a nice banana split."

 Deesi fẹran lati maa jokoo si isọ kétíya Luigi, ki ó sì takurọsọ diẹ pẹlu onisọ yii, ti ó jẹ ara Itali kan ti ki i se elérò buburu

Daisy liked sitting in Luigi's ice-cream parlour and having a little chat with the owner, a positive-thinking Italian.

 Bi Deesi se mú òkè gùn lọ si ọọfisi rẹ, ọrọ ti o jẹ mọ awon ọmọ eniyan kò dùn un mọ.

As Daisy walked up the stairs to her office she felt a little less sore about human beings.

 Bi Deesi se n paarọ bàtà rẹ lọwọ sí sálúbàtà, bẹẹ ni ẹnikan kàn ilẹkun ti ó si wọle wá.

Just as Daisy was changing her shoes to a more comfortable pair, someone knocked on the door and walked in.

 Onisẹ kan ti ó wọ asọ isẹ toketilẹ ni

It was a workman in overalls.

 “Omidan, ẹ jọwọ se ẹyin ni Omidan Deesi Hamitin? Nibo ni ki a gbé awọn eleyii kalẹ sí?” ó n na ọwọ sí àpótí nla meji ti n bẹ ni idasẹle àbágòkè.

"Excuse me miss - are you Miss Daisy Hamilton? Where shall we put these?" pointing to two large boxes on the landing.

 Bẹẹ ni, emi ni Omidan Deesi Hamitin sugbọn ki ni awọn ohun ti ó wà ninu awọn àpótí nibẹ yẹn?”

"Yes, I am Daisy Hamilton but what have you got there - what's in those boxes?"

 “Ẹrọ amu-nnkan-tutú ni eyi ti o tobi yii, kekere sì jẹ ẹrọ ti n pò ẹlẹrindodo. Awọn ti o yàn yii dara o, se o mọ, iru awọn ti ó dara jù ni arọwọto ni yii.”  

"The big one is a fridge and the smaller one is a cappuccino-making machine. You've chosen well, you know, these are the best makes around."

Deesi lọgun pe “Emi ò sọ pe mo fẹ rà awọn yii o,”

"I haven't ordered either of these," exclaimed Daisy.

 “Onisẹ fi dandan mu u pe “Sugbọn orukọ rẹ ni n bẹ lori iwe ẹrù!”

"But it's your name on the delivery note!" insisted the workman.

 “Gbogbo owó ni ó ti wà ni àsanpé. Sá sọ ibi ti maa gbe wọn kalẹ si.”

"It's all paid for - just tell me where to put them."

 Ó kù diẹ ki Deesi kọ awọn ẹrù yii nigbati ó ri ti Franki Baksini pẹlu n wọle bọ wá.

Daisy was just about to refuse the goods when she saw Frank Baccini coming in the door, too.

 “Omidan Hamitin. Mo tọrọ aforijin pe mi ò kàn si ọ lati igba yii wá.

"Miss Hamilton. I'm very sorry I haven't been in touch.

 “Mo rò pe kò bi ọ ninu, mo ti sakiyesi pe o ò ni ẹrọ amu-nnkan-tutú ninu ọọfisi rẹ ati…… ẹrọ ti n pò ẹlẹrindodo yii jẹ iru eyi ti kò wọpọ.

"I do hope you don't mind but I had noticed you didn't have a fridge in your office and... this cappuccino-making machine is a little specialty.

 “O, tilẹ wò naa, sọwedowo rẹ ni yii fun isẹ ribiribi ti o se, pẹlu èènì owó diẹ fun awọn ìnáwó pẹpẹpẹ rẹ”

"Oh, by the way here is your cheque for the excellent work you did, with a little extra for your expenses."

 Franki Baksini ri pe ẹnu ya Deesi, ó fi kun ọrọ pe:

Frank Baccini saw Daisy was astonished and added:

 “Mo lero pe akọwe mi ti maa pe ọ? “Mo lọ irin ajo lati bi ọsẹ meloo diẹ lati lọ gbadun pẹlu iyawo mi tuntun.”

"My secretary did phone you, I hope? I've been away for a couple of weeks on honeymoon."

 Deesi yara sara rẹ giri, Rara, ko buru, kò pè mi –  amọ ko si iyọnu, Ọgbẹni Baksini.

Daisy recovered herself, "Well, no, she didn't - but that's quite all right Mr. Baccini!"

LONWEB.ORG is a private website brought to you by Robert Behar-Casiraghi and Crystal Jones
Tel. +39-370-3269004 - email:

 Our websites: www.lonweb.org  •  www.englishgratis.com  •  www.20ore.com  •  www.scuolitalia.com